1. Home
  2. Naira Marley
  3. Soapy

Soapy

Naira Marley

Ó t'esè'lé bò Yahoo ni babaláwo (Yahoo ni babaláwo) Olè l'everybody Eni ilè mó bá ṣá ni bàráwò (Bàráwò, bàráwò, bàráwò) Mó bá ṣá ni bàráwò Ó t'esè'lé bò (Ó t'esè'lé bò) Yahoo ni babaláwo (Yahoo ni babaláwo) Olè l'everybody Eni ilè mó bá ṣá ni bàráwò Ó fé ṣè'kà fún mi (Ófé ṣè'kà fún mi) Mi ò l'ógùn mo ní Kùránì (Mo ní Kùránì) Mo dè ń ṣ'àdúrà mi Bí n sé ń ṣ'àdúrà mi, Allah ń gbà'dúrà mi (Allah ń gbà'dúrà mi) A ti lo a ti dé (A ti lo a ti dé) Eni orí yo ó dilé (Eni orí yo ó dilé) Ení ba lo l'ó ba dé Ìgbà tí n padà dé ń'ṣe l'ón dé mi l'ádé (Ń'ṣe l'ón dé mi l'ádé) K'ádé k'ó pé l'órí (K'ádé k'ó pé l'órí) Kí bàtà k'ó pé l'ésè (Kí bàtà k'ó pé l'ésè) K'àwon òtá mi kán l'ésè K'àwon [?] kí wón kán l'ésè Inside life, l'oó ti rí Five Alive (L'oó ti rí Five Alive) Inside life, l'oó ti rí Deeper Life (L'oó ti rí Deeper Life) Inside life àwon kan ń jè'yà, àwon kan ń chop life (Inside life) Inside life àwon kan ń ṣ'épè, àwon kan ń j'èwà Jó soapy (Soapy) Kiríkirì ń jó soapy (Kiríkirì ń jó soapy) Jó soapy (Soapy) Ìkòyí prison ń jó soapy (Ìkòyí prison ń jó soapy) Jó soapy Nínú cell EFCC wón ń jó soapy (Wón ń jó soapy) Jó soapy T'ó ò bá ní'yàwó ń'lé k'o jó soapy (Soapy) Soapy (Soapy) Bròdá yì ń jó soapy (Bròdá yì ń jó soapy) Soapy (Soapy) Àbí èyin náà soapy (Àbí èyin náà soapy) Soapy (Soapy) Single father ń jó soapy (Single father ń jó soapy) Soapy Má lo lo Omo t'o bá lo ń soapy (Soapy) Ṣ'o d'ówó mò (Ṣ'o d'ówó mò) Owá so pé òmo Naira (Owá so pé òmo Naira) Ówúwo l'ówó, ìwo ṣáà ṣe sí Naira (Ìwo ṣáà ṣe sí Naira) Ajá fé dè'nà d'ekùn Kékeré ekùn ò mà ń ṣ'egbé ajá (Kò ń s'egbé ajá) Wón ń bé ni, má fòó, àwon náà ò fé wàhálà (Àwon náà ò fé wàhálà) I just want make mama proud (I just want make mama proud) They want to make mama cry (They want to make mama cry) Mama, you gonna cry no more T'e bá sun'kún gan, e ó so'kún ayò (E ó so'kún ayò) Tí n bá ń jó k'e bá n yò (K'e bá n yò) K'órò mí já s'áyò (K'órò mí já s'áyò) Inside life (Inside life) Kú àwon 'cause it's my life (Kú'òn'bè!) Inside life, l'oó ti rí Five Alive (L'oó ti rí Five Alive) Inside life, l'oó ti rí Deeper Life (L'oó ti rí Deeper Life) Inside life àwon kan ń jè'yà, àwon kan ń chop life (Inside life) Inside life àwon kan ń ṣ'épè, àwon kan ń j'èwà Jó soapy (Soapy) Kiríkirì ń jó soapy (Kiríkirì ń jó soapy) Jó soapy (Soapy) Ìkòyí prison ń jó soapy (Ìkòyí prison ń jó soapy) Jó soapy Nínú cell EFCC wón ń jó soapy (Wón ń jó soapy) Jó soapy T'ó ò bá ní'yàwó ń'lé k'o jó soapy (Soapy) Soapy (Soapy) Bròdá yì ń jó soapy (Bròdá yì ń jó soapy) Soapy (Soapy) Àbí èyin náà soapy (Àbí èyin náà soapy) Soapy (Soapy) Single father ń jó soapy (Single father ń jó soapy) Soapy Má lo lo Omo t'o bá lo ń soapy (Soapy)

Share it


※ Songwriter

Azeez Fashola

https://onlyrics.co/en/naira-marley/soapy?lang=yo

Submitted on October 14, 2022 by Anonymous

Comments

You need to be logged in to write a comment. Please login or register to continue.
Naira Marley
The best of
Naira Marley

Release Name or Album Name

Soapy

Release Date

June 28, 2019

Language

language Yoruba

Spotify

Listen song in spotify service

Words

Most Popular Words in Songs

single mama l'oo deeper alive inside t'ese'le life ikoyi naira l'ese want father kirikiri yahoo make barawo prison eyin broda awon babalawo five soapy